Máàkù 11:8 BMY

8 Nígbà náà, púpọ̀ nínú ọ̀pọ̀ ènìyàn tẹ́ àṣọ wọn sójú-ọ̀nà níwájú u rẹ̀. Àwọn mìíràn ju ewéko ìgbẹ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 11

Wo Máàkù 11:8 ni o tọ