Máàkù 12:1 BMY

1 Lẹ́yìn ìgbà tí Jésù pa àwọn olórí ẹ̀sìn lẹ́nu mọ́: ó bẹ̀rẹ̀ síí fi òwe bá wọn sọ̀rọ̀ pé, “Ọkùnrin kan dá oko àjàrà kan. Ó ṣe ọgbà yì i ká, ó sì gbẹ́ ihò níbi tí omi yóò ti máa jáde fún ìtọ́jú ohun ọ̀gbìn. Níkẹyìn, ó gbé oko fún àwọn olùtọ́jú, ó sì lọ ìrìnàjò tí ó jìnnà.

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:1 ni o tọ