Máàkù 12:36 BMY

36 Nítorí tí Dáfídì tìkárarẹ̀, ti ń ti ipa Ẹ̀mí Mímọ́ sọ̀rọ̀ wí pé:“ ‘Ọlọ́run sọ fún Olúwa mi:“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi,títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀ta rẹdi àpótí ìtìṣẹ̀ rẹ.” ’

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:36 ni o tọ