Máàkù 13:4 BMY

4 “Sọ fún wa, nígbà wo ni nǹkan wọ̀nyí yóò ṣẹlẹ̀ sí tẹ́ḿpílì náà? Kí ni yóò sì jẹ àmì nígbà tí gbogbo nǹkan wọ̀nyí yóò ṣẹ?”

Ka pipe ipin Máàkù 13

Wo Máàkù 13:4 ni o tọ