Máàkù 14:11 BMY

11 Inú wọn dùn láti gbọ́ èyí, wọ́n sì pinnu láti fún un ní owó. Nítorí náà ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ àkókò tí ó rọrùn tí òun yóò fi Jésù lé wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:11 ni o tọ