Máàkù 14:16 BMY

16 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì náà sì jáde lọ àárin ìlú. Wọ́n bá gbogbo nǹkan gẹ́gẹ́ bí Jésù tí sọ fún wọn. Wọ́n sì pèsè àṣè ìrékọjá.

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:16 ni o tọ