Máàkù 15:45 BMY

45 Nígbà tí balógun-ọ̀rún náà sì fún Pílátù ni ìdánilójú pé Jésù ti kú, Pílátù yọ̀ǹda òkú rẹ̀ fún Jóṣẹ́fù.

Ka pipe ipin Máàkù 15

Wo Máàkù 15:45 ni o tọ