Máàkù 16:17 BMY

17 Àmì wọ̀nyí yóò sì máa bá àwọn tí ó gbàgbọ́ lọ. Ní orúkọ mi ni wọ́n yóò máa lé ẹ̀mí èsù jáde. Wọn yóò máa fi èdè titun sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 16

Wo Máàkù 16:17 ni o tọ