Máàkù 16:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n nígbà tí wọn sì wò ó, wọ́n rí i pé a ti yí òkúta tí ó tóbi gidigidi náà kúrò.

Ka pipe ipin Máàkù 16

Wo Máàkù 16:4 ni o tọ