Máàkù 3:10 BMY

10 Nítorí tí ó mú ọ̀pọ̀ ènìyàn láradá lọ́jọ́ náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn aláìsàn ló yí i ká, tí wọ́n sì ń gbìyànjú láti fi ọwọ́ kàn án.

Ka pipe ipin Máàkù 3

Wo Máàkù 3:10 ni o tọ