31 Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, ìyá àti àwọn arákùnrin rẹ̀ dé. Wọ́n dúró lóde, wọ́n sì rán ẹnìkan sí i pé kí ó pè é wá.
Ka pipe ipin Máàkù 3
Wo Máàkù 3:31 ni o tọ