Máàkù 4:11 BMY

11 Ó sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin ni a gbà láàyè láti mọ ohun ìjìnlẹ̀ nípa ìjọba Ọlọ́run. Èyí tí ó pamọ́ sí àwọn tí ó wà lẹ́yìn agbo ìjọba náà.

Ka pipe ipin Máàkù 4

Wo Máàkù 4:11 ni o tọ