Máàkù 6:15 BMY

15 Àwọn mìíràn wí pé, “Èlíjà ní.”Àwọn mìíràn wí pé, “Wòlíì bí ọ̀kan lára àwọn àtijọ́ tó ti kú ló tún padà sáyé.”

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:15 ni o tọ