Máàkù 6:25 BMY

25 Ọmọbìnrin yìí sáré padà wá sọ́dọ̀ Hẹ̀rọ́dù ọba. Ó sì wí fún un pé, “Mo ń fẹ́ orí Jòhánù Onítẹ̀bọmi nísinsin-yìí nínú àwopọ̀kọ́.”

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:25 ni o tọ