Máàkù 6:30 BMY

30 Àwọn àpósítélì ko ara wọn jọ sí ọ̀dọ̀ Jésù, wọ́n sí ròyìn ohun gbogbo tí wọ́n ti ṣe àti ohun gbogbo tí wọ́n ti kọ́ni.

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:30 ni o tọ