Máàkù 6:4 BMY

4 Nígbà náà, Jésù wí fún wọn pé, “A máa ń bu ọlá fún wòlíì níbi gbogbo àfi ní ìlú ara rẹ̀ àti láàrin àwọn ìdílé àti àwọn ẹbí òun pàápàá.”

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:4 ni o tọ