Máàkù 6:51 BMY

51 Nígbà náà ni ó gòkè sínú ọkọ̀ pẹ̀lú wọn, ìjì líle náà sì dáwọ́ dúró. Ẹ̀rù sì bà wọ́n rékọjá gidigidi nínú ara wọn, ẹnú sì yà wọ́n.

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:51 ni o tọ