Máàkù 6:56 BMY

56 Ní ibi gbogbo tí ó sì dé, yálà ní abúlé, ìlú ńlá tàbí àrọ́ko, ńṣe ni wọ́n ń kó àwọn aláìsàn pàdé rẹ̀ ní àárin ọjà. Wọ́n sì ń bẹ̀ ẹ́ kí ó jẹ́ kí wọn fi ọwọ́ kan etí aṣọ rẹ̀, gbogbo àwọn tí wọ́n sì fi ọwọ́ kàn án ni a mú láradá.

Ka pipe ipin Máàkù 6

Wo Máàkù 6:56 ni o tọ