Máàkù 7:18 BMY

18 Jésù béèrè wí pé, “Àbí kò sí èyí tí ó yé yín nínú ọ̀rọ̀ náà? Ẹ̀yin kò rí i wí pé ohunkóhun tí ó wọ inú ènìyàn láti òde kò lè sọ ènìyàn di aláìmọ́?

Ka pipe ipin Máàkù 7

Wo Máàkù 7:18 ni o tọ