Máàkù 7:6 BMY

6 Jésù dá wọn lóhùn wí pé, “Ẹyin àgàbàgebè yìí, òótọ́ ni wòlíì Àìṣáyà ń sọ nígbà tí ó ń ṣe àpèjúwe yín, tó wí pé:“ ‘Àwọn ènìyàn wọ̀nyí fi ẹnu wọn bu ọlá fún miṣùgbọ́n ọkàn wọn jìnà sí mi.

Ka pipe ipin Máàkù 7

Wo Máàkù 7:6 ni o tọ