Máàkù 9:13 BMY

13 Ṣùgbọ́n mo wí fún yín pé, Èlíjà ti wa ná, wọ́n sì ti ṣe ohunkóhun tí ó wù wọ́n sí i, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ̀wé nípa rẹ̀.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:13 ni o tọ