2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà tí Jésù sọ̀rọ̀ yìí, Jésù mú Pétérù, Jákọ́bù àti Jòhánù lọ sí orí òkè gíga ní apákan. Kò sí ẹlòmíràn pẹ̀lú wọn, ara rẹ̀ sì yípadà níwájú wọn.
Ka pipe ipin Máàkù 9
Wo Máàkù 9:2 ni o tọ