Máàkù 9:21 BMY

21 Jésù béèrè lọ́wọ́ baba ọmọ náà pé, “Ó tó ìgbà wo tí ọmọ rẹ̀ ti wà nínú irú ipò báyìí?”Baba ọmọ náà dáhùn pé, “Láti kékeré ni.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:21 ni o tọ