Máàkù 9:32 BMY

32 Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ náà kò yé wọn, ẹ̀rù sì bà wọ́n láti bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀, ìtumọ̀ ohun tí ó sọ náà.

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:32 ni o tọ