Àwọn Ọba Keji 1:2 BM

2 Ahasaya ọba ṣubú láti orí òkè ilé rẹ̀ ní Samaria, ó sì farapa pupọ. Nítorí náà ni ó ṣe rán oníṣẹ́ lọ bèèrè lọ́wọ́ Baalisebubu, oriṣa Ekironi, bóyá òun yóo sàn ninu àìsàn náà tabi òun kò ní sàn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:2 ni o tọ