Àwọn Ọba Keji 1:4 BM

4 Ẹ lọ sọ fún ọba pé, báyìí ni OLUWA wí, ‘O kò ní sàn ninu àìsàn náà, kíkú ni o óo kú.’ ”Elija sì ṣe gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:4 ni o tọ