Àwọn Ọba Keji 10:1 BM

1 Ahabu ní aadọrin ọmọkunrin tí wọn ń gbé Samaria. Jehu kọ ìwé ranṣẹ sí àwọn olórí ìlú ati àwọn àgbààgbà ati àwọn olùtọ́jú àwọn ọmọ Ahabu, ó ní:

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:1 ni o tọ