Àwọn Ọba Keji 10:17 BM

17 Nígbà tí wọ́n dé Samaria, Jehu pa gbogbo àwọn ìbátan Ahabu, kò sì fi ọ̀kankan ninu wọn sílẹ̀, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ láti ẹnu Elija.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:17 ni o tọ