Àwọn Ọba Keji 10:29 BM

29 Ṣugbọn Jehu tẹ̀lé ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu, ọmọ Nebati, tí ó mú kí Israẹli bọ ère ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù, tí wọ́n fi wúrà ṣe, tí ó wà ní Bẹtẹli ati Dani.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:29 ni o tọ