Àwọn Ọba Keji 10:31 BM

31 Ṣugbọn Jehu kò kíyèsára kí ó fi gbogbo ọkàn rẹ̀ tẹ̀lé Òfin OLUWA Ọlọrun Israẹli; ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu tí ó mú kí Israẹli hù ni ó tẹ̀lé.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:31 ni o tọ