Àwọn Ọba Keji 10:33 BM

33 láti ìhà ìlà oòrùn Jọdani, gbogbo ilẹ̀ Gileadi ati ti ẹ̀yà Gadi, ẹ̀yà Reubẹni ati ẹya Manase. Láti Aroeri tí ó wà ní àfonífojì Arinoni tíí ṣe ilẹ̀ Gileadi ati ilẹ̀ Baṣani.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:33 ni o tọ