Àwọn Ọba Keji 11:15 BM

15 Jehoiada kò fẹ́ kí wọ́n pa Atalaya ninu ilé OLUWA, nítorí náà ó pàṣẹ fún àwọn olórí ogun, ó ní, “Ẹ mú un jáde, kí ó wà ní ààrin yín bí ẹ ti ń mú un lọ; ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ gbà á là, pípa ni kí ẹ pa á.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:15 ni o tọ