Àwọn Ọba Keji 11:19 BM

19 Òun ati àwọn olórí ogun ati àwọn tí wọ́n ń ṣọ́ ọba ati àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin sin ọba láti ilé OLUWA lọ sí ààfin. Ọba gba ẹnu ọ̀nà àwọn olùṣọ́ wọlé, ó sì jókòó lórí ìtẹ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:19 ni o tọ