Àwọn Ọba Keji 12:4 BM

4 Joaṣi pàṣẹ fún àwọn alufaa pé kí wọ́n máa kó àwọn owó ohun mímọ́ tí wọ́n mú wá sí ilé OLUWA pamọ́: ati gbogbo owó tí àwọn eniyan san fún ẹbọ ìgbà gbogbo ati èyí tí wọ́n mú wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ àtinúwá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 12

Wo Àwọn Ọba Keji 12:4 ni o tọ