Àwọn Ọba Keji 13:14 BM

14 Nígbà tí wolii Eliṣa wà ninu àìsàn tí ó le, tí ó sì ń kú lọ, Jehoaṣi, ọba Israẹli lọ bẹ̀ ẹ́ wò, nígbà tí ó rí Eliṣa, ó sọkún, ó sì ń kígbe pé, “Baba mi, baba mi! Ìwọ tí o jẹ́ alátìlẹyìn pataki fún Israẹli!”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 13

Wo Àwọn Ọba Keji 13:14 ni o tọ