Àwọn Ọba Keji 13:2 BM

2 Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA, ó tẹ̀lé ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu, ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli ṣẹ̀, kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ náà sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 13

Wo Àwọn Ọba Keji 13:2 ni o tọ