Àwọn Ọba Keji 13:25 BM

25 Jehoaṣi ọba, ọmọ Jehoahasi, ṣẹgun Benhadadi ní ìgbà mẹta, ó sì gba àwọn ìlú tí wọ́n ti gbà ní ìgbà ayé Jehoahasi, baba rẹ̀ pada.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 13

Wo Àwọn Ọba Keji 13:25 ni o tọ