Àwọn Ọba Keji 13:6 BM

6 Sibẹsibẹ wọn kò yipada kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ tí Jeroboamu ti mú Israẹli dá. Wọ́n sì tún ń dá ẹ̀ṣẹ̀ kan náà, ère oriṣa Aṣera sì wà ní Samaria.)

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 13

Wo Àwọn Ọba Keji 13:6 ni o tọ