Àwọn Ọba Keji 14:10 BM

10 Nisinsinyii, ìwọ Amasaya, nítorí pé o ti ṣẹgun Edomu, ọkàn rẹ kún fún ìgbéraga. Jẹ́ kí ògo rẹ yìí tẹ́ ọ lọ́rùn, kí ló dé tí o fi fẹ́ dá ìjàngbọ̀n sílẹ̀ sí ìparun ara rẹ ati ti Juda?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:10 ni o tọ