Àwọn Ọba Keji 14:13 BM

13 Ọwọ́ Jehoaṣi tẹ Amasaya, lẹ́yìn náà, ó lọ sí Jerusalẹmu, ó wó odi Jerusalẹmu lulẹ̀ láti Ẹnubodè Efuraimu títí dé Ẹnubodè Igun, gbogbo rẹ̀ jẹ́ irinwo igbọnwọ (400 mita).

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:13 ni o tọ