Àwọn Ọba Keji 14:19 BM

19 Wọ́n dìtẹ̀ mọ́ Amasaya Ọba ní Jerusalẹmu, ó sì sá lọ sí Lakiṣi. Ṣugbọn wọ́n rán eniyan lọ bá a níbẹ̀, wọ́n sì pa á.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:19 ni o tọ