Àwọn Ọba Keji 14:29 BM

29 Jeroboamu kú, wọ́n sin òkú rẹ̀ sinu ibojì àwọn ọba, Sakaraya, ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:29 ni o tọ