Àwọn Ọba Keji 14:3 BM

3 Ó ṣe ohun tí ó dára lójú OLUWA, ṣugbọn kò dàbí ti Dafidi baba ńlá rẹ̀; ohun gbogbo tí Joaṣi baba rẹ̀ ṣe ni òun náà ṣe.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:3 ni o tọ