Àwọn Ọba Keji 15:18 BM

18 Ó ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA títí di ọjọ́ ikú rẹ̀, nítorí pé ó tẹ̀lé ọ̀nà Jeroboamu ọba, ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli dẹ́ṣẹ̀ títí di ọjọ́ ikú rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:18 ni o tọ