Àwọn Ọba Keji 15:23 BM

23 Nígbà tí ó di aadọta ọdún tí Asaraya jọba ní Juda, ni Pekahaya, ọmọ Menahemu jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó sì wà lórí oyè fún ọdún meji.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:23 ni o tọ