Àwọn Ọba Keji 15:33 BM

33 Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba, ó sì jọba fún ọdún mẹrindinlogun ní Jerusalẹmu. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jeruṣa, ọmọ Sadoku.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:33 ni o tọ