Àwọn Ọba Keji 15:35 BM

35 Ṣugbọn kò pa àwọn pẹpẹ ìrúbọ run, àwọn eniyan ṣì ń rú ẹbọ, wọ́n sì ń sun turari níbẹ̀. Òun ni ó kọ́ ẹnu ọ̀nà apá ìhà àríwá ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:35 ni o tọ