Àwọn Ọba Keji 16:9 BM

9 Ọba Asiria gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ̀, ó sì gbógun ti Damasku, ó ṣẹgun rẹ̀, ó pa Resini ọba, ó sì kó gbogbo àwọn eniyan ìlú náà lẹ́rú lọ sí Kiri.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 16

Wo Àwọn Ọba Keji 16:9 ni o tọ