Àwọn Ọba Keji 17:41 BM

41 Àwọn eniyan ilẹ̀ náà sin OLUWA, ṣugbọn wọ́n ń bọ àwọn ère tí wọ́n gbẹ́ pẹlu. Àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ ọmọ wọn sì ń ṣe bẹ́ẹ̀ títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:41 ni o tọ