Àwọn Ọba Keji 18:11 BM

11 Ọba Asiria kó àwọn ọmọ Israẹli ní ìgbèkùn lọ sí Asiria, ó sì kó wọn sí ìlú Hala ati Habori tí ó wà ní agbègbè odò Gosani ati sí àwọn ìlú àwọn ará Media.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:11 ni o tọ